Giwa Samosangudu baba Talabi
Lanre Okunola baba Mutalubi
Deji Laosun baba Siyanbola
Ademola H Adigun baba Rafatu
Ajani Ladipo baba Ashiyanbi
Arigbinjela Osunfemi Oko Sifawu
Akin VòGg Eleso Baba Waidi.
Akindele Adetoye baba Isreali
Abatialapa Rubeeni baba Isiaka
Ijigbende Rafiu baba Silifa.
Olayinka Omisore baba Tafa
Orisajefo Ayojeposaya Onigoolu
Oledepo Dafidi Onigbati Emi mimo!
Adetope Ademiluyi baba Ibeji.
Okuigbe Ogundoyin baba Ikoko Ewa.
E b’oode o!
E b’oota o!
Asiri ti tu!
Oku taa sin ese re nbe n’gboro o!
Owo taa pin, awon to l’owo ti n’beere owo won o!
Olopa ti lo mi n’sokoto mu o!
Walahi ng o si fe d’aruko enikankan o
sugbon l’oju ina l’ewura n’hu’run!
Igbaju ‘gbona lo si mi l’ofun b’igba fitila
ti ntan m’ole sinu okunkun!
Of course this is a simple joke about Dasukigate- whereupon I have used names of some of my friends to illustrate the extent of this unprecedented daylight robbery in high places. Seem everyone got paid- except little old me! Watergate, and the Iran-Contra scandals respectively, shall hopefully compete with Dasukigate for space in the “Hall Of Shame for All other Gates”.
If you look at the above list clinically, there’s a particular name tucked in somewhere there that’s eerily familiar. I wonder if he collected, and if he did, I would really love to know how much the cartoonish, woolly-greyed hair “Uncle-Ruckus” look-alike indeed collected.
Because out of all “kiriminaasi” on the list, this dude “Worked Damn Hardest For His Money!” (All pun intended. Licensing letters forwarded to Donna Summer)
Igbe l’ee sun ee ni m’eri dele!
Image courtesy of Nationonline.ng






