Aporó Èpa Ìjèbú: Egbògi Gbogbonìse!
“In the hazardous entrapment of some dilapidated, but still functioning Molues at a time were found all sorts. Emergency Christ, unnecessary Saviours, eager Pharmacists, immediate Medical Doctors and faster-than-lightning Pickpockets!”- The Molue Show.
Njé won ş’épè fun o ni ndan? Njé aye ńsaa si o ni ndan?! Njé orí re ti buru ti nyo eruku? Njé inu re papa o ti bu bayi, ti o ò ró òòrun fi saa? Njé aye ti rò ó pin? Njé iwo paapa o ti ro ara re pin bi? Njé tó ba yo l’ókèrè awon Ajà adúgbò o máa se ipade àtigbó o abi lati fi eýin won da bátànì si o lara bi? Njé ni igbamiran isó ìdí re a maa rùn ki inu bi iwo funra re bi? Njé isó ohun maa nyo eruku ni ibadi re bii ina l’enu Sàngó Oko Oya bi? Njé ara maa nkan o sàkàsàkà lai nidi bi?
Òré mi o ku oriire, mo ba o yo, tori wipe Ori Adìye kii buru titi ko ye eyin dudu! Ori eni ti o si gbe’ni nii gbe Alawo’re k’oni!
Oro re o gb’ebo, beeni ko gba etutu! B’eeyan beere Idamewa oriibu l’owo re, dakun fi t’òwot’òwo se èpè Ijebu-jesha fun’ru eni bee! Ti emi re baa l’ee gbe dakun ba mi jin iru eni bee ni ìkúùkù ni ipako abi ki o rin jinna die ki o to le onitohun ni ògúlùtu rabata ni ogangan ibi ògo!
Ojutu Isoro Re:
Wo inu le re lo, l’osan gangan bii deede agogo kan, ni deede igba ti Orun ba kan atari. Fi ogbon agba tan Aya re wo inu yara abi sunmo ibi ori pèpéle kan ti o ba wa n’nu ile yin. Ba s’oro didun wipe ki onitohun yo idi s’eyin abi ki o gbe ese kan s’ori pepele. B’oo f’agidi ba s’oro, o l’ee bu o abi ki o wo o tikategbin bii wipe Were ni o! Ogbon bayi l’okuin fi nse baale Obiin!
IKILO PATAKI! Dakun ma si ile wo lo, abi ki o re ka aya alaya m’ole o! Boo dan iru e wo, aye yoo di eru ole le o lori, won yoo si te o l’ódá!
Fi enu ko Aya re l’enu, fi owo si abe buba re ko si se ayewo omú ayaa re boya won wa ni ipo! Dakun fi suuru ra awon koko ori omú wonyi, dakun mo ra won bi igba omode ba nra idi Òkòtó o! Fi ika meji ra won bii igba Alfa Jinadu baa nfi Tesibiu da aniyan si Waidu! Ti Aya re ba ti lee so ori ko, idaniloju wa wipe, Olorun ni ife re, adura re si ti fee maa gba bo diedie! Dakun fi ahon re la ibi orun re, fi ahon re ro eyin eti re ti o kangun si o! Ti sibi obe abi igbale owo re ba fi lee jabo lairotele abi ti iro idi re ba s’eesi tu sile, awon Irunmole Oloore Ofe ti wo inu ile yin nu’un! Iyanu ile aye re feree setan lati ya Adeboye, Oledepo, abi baba wa Ifayemi Elebuibon lenu na. Siun bayi lo ku!
IKILO PATAKI! Dakun ma se kanju! Ma si sare gun oke agbara! Oju lasan ko la gb’omo l’owo ekuro.
Rora ga eyin Aya re sile. Suuru! Suuru! Ma se oro Émí, ni oro Wiriwiri! O ya fi owo mejeeji mu Aya re ni ibi ibadi, jeki abòdan idi re ru gale seyin! Jeki won dabi igi Àràbà leyin oko Agbégilódò. Ni akoko yi, fi owo to igbo Sùùrù re s’egbe kan, fi ika ti o ba mo daada, ti eekanna re k’ogun bii eekanna eye Asa tabi ti Awodi bo ile ooru re. Ti omi iseleru die ba r’egun sara ika be, ti o si funfun balau bii Miliki Olope, ami idaniloju leyi wipe: régí ti se régí fun o nu’un! Dakun fi gbogbo agbara gbe Kondo ti e jade nnu Kembe, ni asiko yi o ye ki erù Kondo yi ti wuwo dada! Ti ko ba wuwo, a je wipe okan nnu awon orogún iya re ti fi èpè ‘gbona ta o l’ore! Adura re o si lee gba rara, tori wipe a kii fi tipatipa “le Okò to ba ti ku!” Yato si eyi ti Kondo re bo inu Ile Ooru Aya re.
IKILO PATAKI! ESO PELE BI EJO TI N’GUN IGI AGBON NI KO MA WOLE JADE O! DAKUN MA SO ARA RE DI SOKOTI ALAGBEDE ORUN TI NKAN ÒÒLÙ MO IRIN GBIGBONA O!!!
Bayi ni koo ma se ise èmí yi lo pelu ifarabale ati suuru. Leyin iseju meji, bere si da aniyan. Gbe ohun s’oke! Awon edun okan re gbogbo, jowo bere si so won. Ti Aya re ba si nse “Amin” si adura re, idaniloju wipe adura re o ti goke dada nu’un! Ti o ba ngba adura wonyi sugbon ti Aya re ko lee se Amin to rinle dodo mo, ti nwírú, ti nwírù, ti oro re dabi oro eni Ìgbóná abi Ogun Oru tabi ti Efori Túúlu nba’ja, idaniloju ni eyi wipe, irinajo oriibu re ti fee d’opin.
O ku oriire! Mo ba o yo!
Pic courtesy of Aderemi Adesoji Ajagunna.






